1/91
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
Àárọ̀
Morning
Ọ̀sán
Afternoon
Ìrọ̀lẹ́
Evening (4pm - 7pm)
Alẹ́
Night (7pm +)
E̩ kú
Good (for greetings)
Ẹ káàárọ̀
Good Morning
Ẹ káàsán
Good Afternoon
Ẹ kúrọ̀lẹ́
Good Evening (4pm - 7pm)
Ẹ káalẹ́
Good Evening (7pm +)
Ó dàárọ̀
Goodnight
Ó dàbọ̀
Goodbye
Ẹ kúulé
Hello (On returning home)
Ẹ káàbọ̀
Welcome
Báwo ni?
How are you?
Dáadáa ni
Fine
ìwo ńkọ́?
And you?
Ẹ ṣeun
Thank you
Ẹ ǹlẹ́ o
Hello
Pẹ̀lẹ́
Sorry
mo
I
Sé
Question Marker
yé
to understand
Kí ni?
What?
Orúkọ
Name
ẹ
your (younger people)
Kí lorúkọ ẹ?
What is your name?
Mi
My
ni
is
Orúkọ mi ni ...
My name is ...
Níbo?
Where?
gbé
to live
Níbo lò ń gbé?
Where do you live?
Mò ń gbé ní ...
I live in ...
ìlú
Town/city
O/ìwọ
you
wá
to come
láti
from
Ìlú wo lo ti wá?
What town are you from?
Mo wá láti ìlú Èkó
I come from Lagos
Rárá
No
Bẹ́ẹ̀ni
Yes
Jọ̀ọ́
Please
Ẹbí
Family
Ìyá
Mum
Bàbá
Dad
Ẹ̀gbọ́n
Older sibling
Àbúrò
Younger sibling
Ìyàwó
Wife
Ọkọ
Husband
Ọmọ
Child
Obìnrin
Female
Ọkùnrin
Male
Rẹwà
Beautiful
Ìyá mi rẹwà
My mom is beautiful
Ta ni?
Who?
Àti
And
Ṣùgbọ́n
But
A
We
nífẹ̀ẹ́
to love
sọ
to say
ní
to have
Kúrú
short
ga
tall
Ó
he/she
wọn
their
Ilé
House
Àga
Chair
Tábìlì
Table
Ilẹ̀kùn
Door
Abọ́
Plate
Ṣíbí
Spoon
Dìde
To stand
Jókòó
To sit
Jókòó síbí
Sit here
Ṣí
Open
Ṣí ilẹ̀kùn
Open the door
Ẹ̀yin
You (plural)
yín
Your(plural)
wa
Our
wọn
them
ibí
here
ibẹ̀yẹn
there
Fún
to give
tì
to close
lábẹ́
under
lórí
on
nínú
in / inside
wà
to be
sílẹ̀
down (put)
fi
to put
wá sí ilé mi
come to my house
èmi / mi
me