1/37
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
Work (to senior/group)
Ẹ kúuṣẹ́ o
Work (to junior)
Kúuṣẹ́ o
Sitting (to senior/group)
Ẹ kúùjókòó o
Sitting (to junior)
Kúùjókòó o
Formal Sitting (to senior/group)
Ẹ kúùkàlẹ̀ o
Formal Sitting (to junior)
Kúùkàlẹ̀ o
Standing (to senior/group)
Ẹ kúùdúró o
Standing (to junior)
Kúùdúró o
Dancing (to senior/group)
Ẹ kúujó o
Dancing (to junior)
Kúujó o
Enjoyment (to senior/group)
Ẹ kúùgbádùn o
Enjoyment (to junior)
Kúùgbádùn o
Viewing/Watching (to senior/group)
Ẹ kúùwòran o
Viewing/Watching (to junior)
Kúùwòran o
Celebration/Festival (to senior/group) (Yearly)
Ẹ kọ́ọdún o
Celebration/Festival (to junior) (Yearly)
Kọ́ọdún o
Celebration/Festival (to senior/group) (Survive the Year)
Ẹ kúùyèdún o
Celebration/Festival (to junior) (Survive the Year)
Kúùyèdún o
Benefatee to Benefactor on Expenses (to senior/group)
Ẹ kúùnáwó o
Benefatee to Benefactor on Expenses (to junior)
Kúùnáwó o
Readiness (to senior/group)
Ẹ kúùmúra o
Readiness (to junior)
Kúùmúra o
Formal Speech (to senior/group)
Ẹ kúùsọ̀rọ̀ o
Formal Speech (to junior)
Kúùsọ̀rọ̀ o
Meal Table (Guest to Host) (to senior/group)
Ẹ kóońjẹ o
Meal Table (Guest to Host) (to junior)
Kóońjẹ o
Meal Table (Host to Guest) (to senior/group)
Ẹ wáá bá wa jẹun o
Meal Table (Host to Guest) (senior to junior)
Wáá bá wa jẹun o
Meal Table (Host to Guest) (junior to junior)
Wáá bá mi jẹun o
Welcoming (to senior/group)
Ẹ káàbọ̀ o / Ẹ kúùrin o
Welcoming (to junior)
Káàbọ̀ o / Kúùrin o
Arrival (from person arriving) (to senior/group)
Ẹ kúulé o
Arrival (from person arriving) (to junior)
Kúulé o
Arrival (to person arriving) (to senior/group)
Ṣé dáadáa ni ẹ dé o? / Ṣé dáadáa ni a dé o?
Arrival (to person arriving) (to junior)
Ṣé dáadáa ni o dé o?
Departure (to person departing) (to senior/group)
Ẹ kílé o
Departure (to person departing) (to junior)
Kílé o
Departure (both leaving)
Ó dìgbà o / Ó dàbọ̀ o / A óò fire pàdé o / A óò pàdé láyọ̀ o / Ayọ ni o! Ire o! / Ire o