1/212
Past and Future Actions/Pronouns/Numbers up to `1000
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
Kíní o ń ṣe
What are you doing
Mò ń
I am
Mo/Mi o
I am/I am not
A/A ò
We are/We are not
O/O ò
You are/You are not
Ẹ/Ẹ ò
You guys are/You guys are not
Ó/Kó
He/She are/He/she are not
Wọ́n/Wọ́n o
They are/They are not
Rá/Fá
To Crawl
Sunkún
To crawl
Gé igi
Cut tree
Gé koríko
Cut grass
Ge ejá
Cut fish
Ge eran
Cut meat
Lu ìlù
Beat drum
Gun ígi
Climb tree
Gun Àpáta
Rock Climb
Kíni o máa ṣe
What will you do?
Mo máa
I will
Ṣe o máa
Are you going to
Kíni o máa jẹ (ni ola)
What will you eat (tomorrow)
Kíni ó máa jẹ
What will they eat
Ó máa jẹ
They will eat
Kíni wọ́n máa ṣe ní àáro ọ̀la
What will they do tomorrow morning
Ní ọ̀túnla
Next tomorrow
Ní Òpìn ọ̀sẹ̀
Weekend
Mi
Me
(R)E
You
(R)È
Him/Her/It
Wa
Us
Yin
You guys
Wón
Them
Emi
Myself
Ìwo
Yourself
Oún
Himself/Herself
Àwa
Ourselves
Ẹ̀yin
Yourselves
Àwọn
Themselves
Ogójì
40 (20×2)
Àádóta
50 (10-20×3)
Ọgọ́ta
60 (20×3)
Àádọ́rin
70 (10-20×4)
Ọgọ́rin
80 (20×4)
Àádọ́rùnún
90 (10-20×5)
Ọgọ́rùnún
100 (20×5)
Àádọfà
110 (10-20×6)
Ọgọ́fà
120 (20×6)
Àádóje
130 (10-20×7)
Ogóje
140 (20×7)
Àádọ́jọ
150 (10-20×8)
Ọgọ́jọ
160 (20×8)
Àádọ́sànán
170 (10-20×9)
Ọgọ́sànán
180 (20×9)
Àádọ́wàá
190 (10-20×10)
Igba
200
Ookanlénígba
201
Eéwàálenígba
210
Ogúlénígba
220
Àádótalenígba
250
Ookandinlogorununlenigba
299
Ọ̀ọ́dúnrún
300
Irínwó
400
Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta
500 (100-200x3)
Ẹgbẹ̀ta
600 (200×3)
Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin
700 (100-200×4)
Ẹgbẹ̀rin
800 (200×4)
Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún
900 (100-200×5)
Ẹgbẹ̀rún
1000 (200×5)
Oja
Market
Eèlòóni
How much?
Meloo ni
How many
Ṣé kò gba
Can I pay
Ṣé kò dín ní
Can you take off
Kò gbà/dín
No
Ó gbà
Yes
Eélòó ni jálẹ̀
How much is the last price
Ẹmu wá
Bring the goods
Ẹgba owó
Take the money
Ṣe ajé ń wo igba
I hope the market is doing well
Oti wanjo
It is too expensive
Àga
Chair
Àjà
Ceiling
Àpẹẹrẹ
Example
àròpọ̀
The sum of
Àwòrán
Picture
ẹfun-Ìwọ̀ké, ṣọ́ọ̀kì
Chalk
Fáìlì
File
Fèrèsé
Window
Fídíò
Video
Gbólóhùn
Sentence
Ìdánwò
Exam
Ilé
house
Ilẹ̀kùn
Door
Iná
Light
Ìrésà, Ìpàwérẹ́
Eraser
Ìṣirò
Mathematics
Ìwé-Ìkọ̀wé
Notebook
Ìwée gíráma
Grammar book
Ìwé-ìtumọ̀
dictionary
Kííbọọ̀dù, àtẹ-ìtẹ̀wé
Keyboard