1/24
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
lálá to ròkè
ilè lòn bọ́
the okro that goes up will come down
A kìí du orí olórí
káwodì gbé tẹni lọ
You do not protect another person’s head while the eagle takes away yours
ojú la rí
ọ̀rẹ́ ò dénú
We could see the smiles/face, the frienship is not genuine
ẹni tí ó bá mú kọ́kọ́rọ́ òkánjúwà lọ́wọ́
ilẹ̀kù àdánù ní o fi ṣi
anyone that holds the key of covetousness will open the door of loss
a kìí bọ́ sómi tán
ka ma kí gbe òtútù
we do not enter the water completely and complain of cold
kí lorí lọ bẹ́
to fi waro ọwọ́
what did you see in the soup tha made you stop eating
àyà níní
o jú ògùn lọ
meaning boldness is greater than charm
ẹnu onì ìkan
lati n gbọ pọ̀ún
we hear the crunch of garden egg from the eater
ìgbá another name for garden egg
àtira ibọn kò tó àtira ẹ̀tu, ọjọ́ kan là rà ìbọn, ojojúmọ́ là n rà ẹ̀tu.
Buying a gun is not the same as buying gun powder, we buy a gun one day but buy gun powdee everday
afínjú tó fẹ bá ẹní pàfọ̀ jìjàkadì….
….kó setán àti wẹ̀wù àbàtà
a neat person who wants to fight with someone dirty (someone who covers himself with mud) should be ready to get dirty.
ajègbodò tó n wa….
….ẹni kúnra
someone who eats yam from the new season when they aren’t supposed to is looking for someone to join him.
the history of this is the king always eats the new yam from the season first and ègbodò is the new yam so when someone decides to eat the yam, it is done in secret that is why ajègbodò is looking for someone to eat with him.
àfòpiná tó ní òun yíò pa fitílà….
….ara rẹ̀ ni yíò pa
insect attracted to light that says it will put out the lantern will only kill itself
àgbájọwọ́ la fií sọ yà….
….àjèjè/àjòjì ọwọ́ kan kò gbérù dé orí
there is strength in unity, the feeble/strange hand does not carry a load to the head.
wọń ní afọ́jú o ò taná alẹ́….
.…ó ní àtọ̀sán àtòru, èwo lòún rí níbẹ
they asked the blind man why he did not switch on the night lantern and he replied, both day and night, which one can I see.
bí a bá ríá òkú ìkà nilẹ̀, tí a tá ní ìpa….
....ika dí mejì
if you see the corpse of a wicked person and kick it, the wickedness is doubled
ọ̀rẹ́ o si mọ́….
.…ka ré ni bá rìn ló kù
true friends don’t exist anymore, companions remain
k’ari kara, ka ri ka ma san….
.…ara ai san Ikeji ole
to view a product and proceed with a purchase, to purchase a product and fail to pay for it, it is the act of not buying that is similar to stealing
ọjọ́ gbogbo ni ti olè….
....ọjọ́ kan ni to lóhun
everyday for the thief, one day for the owner
àgbà kìí wà lójà….
….kìí orí ọmo titun wọ
an elder cannot be in a market place that the head of a new born baby will
ọ̀rọ̀ àgbà tí ọ̀ ṣẹ ní àárọ̀….
….á ṣẹ lójú alẹ́
the statement an elderly says that fails to come true during the day will come through at night
olè tó gbé kàkàkì ọba….
....níbo ní yòó ti fọ́n?
a thief who stole the king’s trumpet will realize he has no place to sound it.
isé dé, ọmọ aláṣe jeun….
….owò dè, ọmọ aláse là
work puts food on the table but business builds wealth
ẹni tó ba fí iṣu tí kò jiná gún yán….
....ó din dandan kó jẹ iyán tó l’ẹ́mò
someone who uses undercooked yam to pound will certainly eat pounded yam that has lumps.
Tí a bá rí ọ̀lẹ, tí a pèé ní olè….
….tó ba bèrè “kí lohún jí”, a ma bi “kí lo n jẹ”
If you see a lazy person and call him a thief, if he asks “what did he steal” and we will ask “what are you eating”
bí ebi bá ń pani ká wí
èwo ní tò bá kọ lù mi, ma gba iṣu ọwọ́ rẹ
if you are hungry, say so, which one is “if you hit me, i will collect the yam you are holding”