1/17
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
ìdùnú
Happiness
Ìbànúje
Sadness
Ìbe ̣̀ru
Fear
Ìbínú
Anger
Itiju/Idojuti
Shame
Ifura
Suspicious
Ironu
Thinking
Inú mi dùn púpo
I am so happy
Inú mi máa ń dùn láti...
I am always happy when...
Inú Adé kò dùn nítorí èsì ìdánwò re ̣̀ kò dára.
Ade isn't happy because of his test results
Jo ̣̀wo ̣́, máṣe banúje ̣́ o ̣̀re ̣́ mi, ara màmá máa yá.
Look, don't be sad my friend, your mom will be okay
Inú mi kò dùn nítorí ebi ń pa mí.
I am not happy because I am hungry.
Má be ̣̀rù
Don't be scared
Oorun ń kùn mí
I am sleepy
Òǹgbẹ́ ń gbẹ́ mi
I am thirsty
Òtútù ń mú mi
I am cold
Ooru ń mú mi
I am hot
Inú ń bí mi
I am angry