Looks like no one added any tags here yet for you.
Sùn
Sleep
Jẹun
Eating
Kọrin
Singing
Gbá bóòlu
Playing Ball
Wa kèkẹ́
Biking
Sáré
Running
Mu omi
Drink Water
Wẹ́
Bathing
Jẹ písá
Eating pizza
Fọ ẹnu
brushing teeth
gbà géèmu
Playing games
Se irun
Doing hair
Dalẹ̀ nù
Taking out the trash
Tọ̀
Peeing
Yàgbẹ́
Pooping
Gbọ́ orin
Listening to music
Wo fíìmu
Watching a movie
Kàwé
Reading
Gbàdúrà
Praying
Fọ abọ́
Doing dishes
Fọ mọ́ tò
Cleaning car
Lọ Aṣọ
Ironing clothes
Nu ile
Mopping
Kun èékáná
Painting nails
Gé'/ré èékáná
Cutting nails
Fọ aṣo
Laundry
Ya àwòrán
Drawing a picture
Gbá ilè
Sweeping
Pe ọ̀re
Call a friend
Wa ọkọ̀
Driving a car
So oúnjẹ
Cooking food
Ra eposí ọkọ̀
Filling a car with gas
Ṣe ìdaraya
Working out
Tọ́ju aja
Walking dog
Tọ́jú ọmọ
Comforting child
Gẹ irun
Cutting hair
Ṣe kílàsì
Teaching
Kọ ìwé
Writing
Lọ èso
Making a smoothie
Dòdò
Plantains
Sípàgétì
Spaghetti
Ẹyin Sísè
Boiled Eggs
Ẹpà
Peanuts
Àgbàdo
Corn
Písà
Pizza
Ọsàn
Orange
Ọ̀gẹ̀dẹ̀
Banana
Ìbẹ́pẹ
Papaya
Àgbáyun
Berries
Ata rodo
Habanero Pepper
Tà tàse
Bell Pepper
Iyò
Salt
Tòmátò
Tomato
Àlùbọ́sà
Onion
Òróró
Vegetable oil
Epo
Palm Oil
Ọtí
Beer
Wàrà
Milk
Ṣe
Do/Did/Are/Is/Where/etc.
Kíni
What?
Ṣé o fẹ́ran láti sùn
Do you like to sleep?
Béè ni, mo fẹ́ràn láti sùn
Yes, I like to sleep
Kíni o fẹ́rán làti ṣe
What do you like to do
Mo fẹ́ràn láti
I like to
Kíni o fẹ́rán làti jẹ
What do you like to eat
Ṣé o fẹ́rán láti jẹ
Do you like to eat
Mo fẹ́ràn láti jẹ
I like to eat
Kíni oò fẹ́ran láti ṣe
What don’t you like to do
Mi ò fẹ́ràn láti
I don’t like to
Kíni oò fẹ́ran láti jẹ
What don’t you like to eat
Mo dúpẹ́
I am grateful
Ọjọ
Day
Òni
Today
Àná
Yesterday
Ọ̀la
Tomorrow
Ní àárọ
This/That morning
Kinni o se ni osan àná
What did you do yesterday afternoon
Ọ̀sẹ̀ ti ó kọja
Last week
Ọsẹ yìí
this week
Ọ̀sẹ̀ ti ó ń bo
Next week
Oṣù ti ó kọja
Last month
Oṣù yìí
This month
Oṣù ti ó ń bo
Next month
Ọdun
Year