1/21
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
Bàbá
Father
Màmá
Mother
Ọmọ
Child
Bàbá Àgbà
Grandfather
Màmá Àgbà
Grandmother
Ọmọ-ọmọ
Grandchild
Ọkùnrin
Male
Obìnrin
Female
Ẹgbón
Older sibling
Àbúrò
Younger sibling
Ẹgbón/Àbúrò Bàbá Ọkùnrin
Uncle (Paternal)
Ẹgbón/Àbúrò Bàbá Obìnrin
Aunt (Paternal)
Ẹgbón/Àbúrò Màmá Ọkùnrin
Uncle (Maternal)
Ẹgbón/Àbúrò Màmá Obìnrin
Aunt (Maternal)
Àkọ́bi
First-born
Àbíkẹ́yìn
Last-born
Baálé = Bàbá Ile
Head of house
Ọkọ
Husband
Ìyàwó
Wife
Àlè
In-law (distant)
Àna
In-law (direct)
Ìran
Generation