Looks like no one added any tags here yet for you.
Ọrọ̀ Àsopọ̀
Conjunctions
àti
and
pẹ̀lú
with
àfi
except
bákan náà
moreover
ní àfikun
in addition
kódà
in fact
ṣùgbọ́n
but
tàbí
or
nítorípé
because
yàtọ̀ sí
apart from
nítorí náà
therefore
tún
also
Oríṣìí Ìbéèrè
Questions
Kíni
What
Níbo
Where
Tani
Who
Nígbàwo
When
Ṣé
Do
Báwo ni
How
Èwo
Which
Kílódé
Why
ỌRỌ ATỌKÙN
Prepositions
Òkè àti ìsàlẹ̀
Up and Down
Iwájú àti ẹ̀yìn
Front and Back
Dúró àti Jókòó
Stand and Sit
Ẹ̀gbẹ́ àti àárín
Side and Inbetween
Orí àti abẹ́
Top and Bottom
Inú àti ìta
Inside and Outside
ìdojúkọ
Opposite
Apá òsì
Left [hand side]
Apá òtún
Right [hand side]
Nígbàtí
While
Bóyá
Maybe
Bámi
Help me
Nı́ bı́i
About
Omo yara
Roomate
Mi ò mọ̀.
I don’t know
tí
when
ibẹ̀
there
Mo ti ṣe tán
I am done
Mo ti fẹ́ẹ̀ ṣe tán
I am almost done
Má pẹ̀ẹ́
Don’t take too long
Ṣé o ti fẹ́ẹ̀ tán?
Are you almost done?
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti fẹ́ẹ̀ tan.
Yes, I am almost done.