1/81
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
|---|
No study sessions yet.
mọ̀
to know
nà
to flog
náà
the
àárọ̀
morning
ayọ̀
joy
aṣọ
cloth
ọkọ
husband
ẹ̀kọ́
lesson
ọwọ́
hand
ọ̀gá
master / boss
ìròlẹ́
evening
ọ̀sán
afternoon
ọ̀fọ́
bereavement
ọjọ́
day
ọ̀rọ̀
word
ọlọ
grind stone
wọn
they
ìtàn
story
ọgbọ́n
wisdom
iná
fire
ọmọ
child
iyán
pounded yam
ẹ̀gbọ́n
older sibling
ìyẹn
that (noun)
yẹn
that (adjective)
hẹn
yes; in fact
ọ̀nà
road
ìbọn
gun
ẹran
meat; animal
ọpọ́n
tray
ìsìn
worship
ẹni
person (indefinite)
pín
divide
imí
faeces
jìn
be deep
mì
swallow
yìn
praise
èmi
I
fún
give
mú
take
sùn
sleep
ẹmu
palm wine
dùn
be sweet
nù
wipe
kùn
grumble
ẹnu
mouth
àpò
bag
òpó
pole
igbó
forest
kíjìpá
blanket
mu
drink
omi
water
imú
nose
àgbẹ̀
farmer
àpótí
box
àgbà
elder
ọpẹ́
thanks
ẹgbẹ́
group; association
pẹ́
be late
àgbàlagbà
old person
pọ̀
be plenty
ata
pepper
àpà
scoundrel
àtà
tadpole
ìgbà
time; period
igba
two hundred
igbá
calabash
ìgbá
locust bean seed
igbà
climbing rope
itan
thigh
ọ̀wọ̀
respect
ọwọ̀
broom
ọ̀wọ́
group
sún
scoot
sún
spring up
kọ́
build
kọ
write
kọ̀
reject
ró
wrap around
ro
drip
rò
think
ìgbà
time