1/50
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced | Call with Kai |
|---|
No analytics yet
Send a link to your students to track their progress
àgbàdo
corn
aṣọ
clothing
bàbá
father
bọ́ọ̀lù
ball
eré
play
ẹmu
palm wine
ẹyin
egg
Ìbàdàn
a city in southwest Nigeria
ilé
house
ìrẹsì
rice
kóòkì
Coke
mọ́ínmọ́ín
a meal made from black-eyed peas
Ọ̀gbẹ́ni
Mr. (funny) “please leave me alone”
olùkọ́
teacher
ọmọ
child
orúkọ
name
owó
money
ọbẹ̀
stew
aagoo yín
your clock/wristwatch
a dúpẹ́
thank you
aṣọọ̀ rẹ
your clothes
bàbáa Fúnmi
Fúnmi’s father
iléè rẹ̀
his/her house
ìwéè mi
my book
o ṣé
thank you
ó tì
no
owóo wọn
their money
ọjọ́ ìbí
birthday
ọkọ̀ọ wa
our vehicle
gbá
to kick/hit
fẹ́
to want
gbé
to live
jẹun
to eat
kàwé
to read a book
mu
to drink
ní
to have
báwo ni?
how are you?
ṣúgbọ́n
but
tàbí
or
kí ni?
what?
kí ni nǹkan?
how are things?
ṣé àlàáfíà ni?
how are you/how are things?
ṣé dáadáa ni?
how are you/how are things?
ṣé nǹkan ń lọ?
are things going well?
ṣé wà á jókòó?
would you like to sit down?
àlàáfíà ni
fine/I am fine/things are fine/peace
dáadáa ni
I am fine
káàbọ̀ o
you are welcome (here)
kó o kí wọn
greet them (members of your family)
mo kàn sáré wá kí ẹ ni
I quickly came to say ‘hi’ to you
ó rẹ̀ mí díẹ̀
I am a little tired