1/11
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
mo ń dunú
I’m happy
mo ń bínú
I’m angry
mo fajúro
I’m sad
ara mi ń gbóná
I’m hot
ara mi tutù
I’m cold
mo n sàárẹ̀
I’m sick
ebi ń pa mí
I’m hungry
Òngbẹ ń gbẹ́ mi
I’m thirsty
Ó rẹ̀ mi
I'm tired/exhausted
Orun ń kùn mí
I'm sleepy
Ojú ń tìmí
I’m shy
Ìfẹ́ ń pa mí
I'm in love