1/18
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced |
---|
No study sessions yet.
ní ẹyẹọ̀sọka
swiftly, quickly
fi orí okò sọ ọ̀dúnrún
go straight to the point
ènìyàn jẹ iyán kan igbá
to meet
pa ẹ̀kẹ́ lu
to discuss
ó fi orí jọ eja, ó fi ìrù jọ akan
the head is similar to a fish, the tail is similar to a crab. fish means unsuccessful, tail means successful; unsure of the outcome
k’áwó bọtan
to be lazy
gbé ìgunnu
to be unwise
gun eṣin abónímú
climb a horse with a bruised nose- put yourself in danger, overstep your boundary.
bóde pàdé
to meet the occasion
júba èhoro
to pay homage to the rabbit, to rub away
fi àdàgbá rọ̀
to conclude, to finish something
fí ẹnu kọ
to say what you are not meant to say
fimúfínlẹ̀
to find out the root of something
láníountán kan ò ní ìwo esin
no one has everything in this world because there is no horse with horn in this world. kò sé yan tó pe tán.
ènìyàn fidí fọ igbà yangan
to complicate matters, ko dà ọ̀rọ̀ tí o ti n ní ojú ìtú télè rú pátápátá
ọwọ́ pálábá èyàn sègi
to be caught
gbé pẹ́rẹ́igi ka iná
to start a fight
ọ̀fọ́ọ̀n tọ̀ sí gbẹ́gírí
a rat/thief pees in gbegiri meaning something has gotten bad
pa ènìyàn ní ẹsẹ̀dà
to escort someone halfway