1/4
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced | Call with Kai | Chat |
|---|
No analytics yet
Send a link to your students to track their progress
Nib lo n gbe?
Oruko mi ni samaya. Mo n gbe ni atlanta ni georgia. Mi je adugbo to dake roro. Oruko adugbo mi hagger hills. Ile mi wa ni opopana hagger. Ile mi wa ni itan mei pelu aja-ile. Ile eko alakoobre wa ni apa otun. Papa-isere, soosi, ile epo shell, ile idaraya, baanki truist, ile ituja, ati ile itaja wa ni apa osi. mo feran nitoripe mo n gbe pelu mi mama. Ile wa ni awon itan meji pelu yara isun marun ati baluwe merin. Iwo nko?
Kini o maa n se ni ojooumo ati osoose?
Ni araaro, mo maa n sun aago mejo. Leyin mo maa n lo mi telifoonu lati mogbon iseju. Leyin naa mo maa n fo enu, fo oju mi, ati ya irun. Leyin ni mo maa n wa aso fun oni ati jeun. Leyin naa, mo maa n rin lo si kilassi ni aago mewaa. Ni osan, mo maa n lo si kilassi chemistry. Leyin naa rin lo si ile-ikawe fun ko iwe tabi rin lo si ile fun sun. Leyin naa, mo maa n jeun ounje. Ni aleale, mo maa n pe ore pelu mama mi ati ore mi. Leyin naa mo maa n we ati jeun ounje ale. Mo maa n nu ile ati wo telifisonu ati sun ni aago mejila oru. Ni afikun, ni osoose, mo maa n fo aso ati dana ounje ale.
Suma Insimi
Eyin suma, mo rin irinajo ile si Atlanta ni Georgia. Nigabti o wa ni Atlanta, mo sinmi lati owo awon fiimu ni ile. Mo pelu, se eekanna ati se irun je insimi. Mo pelu, rin irinajo si Orlando ni Florida meji wo ebi mi. Mo pelu, mo wo sinnima, rira li oja, wiwe, ati rin naa Atlanta Beltline pelu ore mi. Ni afikun, mama mi ni ati mo lo si soosi, rira li oja, ati jẹun ni awọn ile ounjẹ. Yato si yen, mo rin irinajo si Peurto Rico o n sinmi. Mo pelu, mo wa nile mo on nikan akoko.
Alo (lessons)
Eko naa mo ko eko lati alo ni iwa yara mu/imo egbon eko o le je o dara ju iwo. Ninu itan alo, naa ajapa le gba li emi naa erin lati owo naa erin. Yato si, naa ajapa jije kekere lati naa erin. Mo pelupelu eko, lati iwo ko ye ki gbagbo kini awon eniyan maa n so fun o nitoripe o le je iro. Ninu itan alo, naa erin gbagbo naa ajapa nigba ti o so iro fun un. Bakan naa, lati alo o ni opolopo eko ninu re!
Alo (similarities/differences)
Alo yoruba ati alo american maa n omode. Pelupelu, mejeji alo won maa n fi alo omode logobon/eko. Ni afikun, ni alo yoruba ati alo american agbalagba lo maa n pa alo. Sugbon, won yato nitoripe alo yoruba won so o ninu egbe kan ati alo american won so fun olukuluku. Pelupelu, alo american awon omode kekere ati alo yoruba won awon odo ati awon agbalagba. Ni apapo, mejeji alo yoruba ati alo american le ko awon eniyan ni awon eko.