1/15
Looks like no tags are added yet.
Name | Mastery | Learn | Test | Matching | Spaced | Call with Kai | Chat |
|---|
No analytics yet
Send a link to your students to track their progress
Ebi ń pa mi
I am hungry
Mo fẹ́ jẹ oúnjẹ
I want to eat food
Wá jẹ́
Come and eat
Wá gbà
Come and take / come and receive
Ṣé o gbọ́ mi?
Did you hear me?
Gbogbo wọn
All of them
Rárá
No
Bẹ́ẹ̀ni
Yes
Ẹ ṣe
Thank you
Ẹ dúpẹ́
We are grateful
Ẹ ṣe púpọ̀
Thank you very much
Mo gbọ́
I understand / I hear you
Mi ò mọ̀
I don't know
Ẹ má bínú
I'm sorry / please don't be angry
Ẹ pẹ̀lẹ́
Sorry
Mo wà dáadáa
I am fine