yoruba self introduction terms

0.0(0)
Studied by 0 people
call kaiCall Kai
learnLearn
examPractice Test
spaced repetitionSpaced Repetition
heart puzzleMatch
flashcardsFlashcards
GameKnowt Play
Card Sorting

1/48

encourage image

There's no tags or description

Looks like no tags are added yet.

Last updated 7:25 PM on 10/13/26
Name
Mastery
Learn
Test
Matching
Spaced
Call with Kai
Chat

No analytics yet

Send a link to your students to track their progress

49 Terms

1
New cards

orúkọ

name

2
New cards

olùkọ́

teacher

3
New cards

akẹ́kọ̀ọ́

student

4
New cards

ara mi

myself

5
New cards

ara rẹ/ara ẹ

yourself

6
New cards

nípa

about

7
New cards

mi

me / my

8
New cards

ìlú

town / city

9
New cards

ìpínlẹ̀

state

10
New cards

orílẹ̀-èdè

country

11
New cards

ṣùgbọ́n

but

12
New cards

nísinsìnyí or báyìí

now

13
New cards

gbé

to live

14
New cards

kọ́

to learn / study

15
New cards

kọ

to write

16
New cards

ṣiṣẹ́

to work

17
New cards

pàdé

to meet

18
New cards

èmi náà

me too

19
New cards

Orúkọ mi ni _____.

My name is ____.

20
New cards

Orúkọ mi ni Aderinoye

My name is Aderinoye

21
New cards

Mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́.

I am a student.

22
New cards

Mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní fásitì Indiana.

I am a student at Indiana University

23
New cards

Mo ń kọ́ nípa _____.

I am studying ______.

24
New cards

Mo ń kọ́ nípa clinical psychology.

I am studying clinical psychology

25
New cards

Mo ń ṣiṣẹ́ ni _____.

I work/working at ______.

26
New cards

Mo ń ṣiṣẹ́ ni recsports

I work at recsports.

27
New cards

Ọmọ ____ ni mí.

I come from ____.

28
New cards

Ọmọ Indiana ni mí.

I come from Indiana.

29
New cards

Mo ń gbé ní ____.

I live in ____.

30
New cards

Mo ń gbé ní Bloomington

I live in Bloomington

31
New cards

Wọ́n bí mi sí _______.

I was born in ___

32
New cards

Wọ́n bí mi sí Avon ni Indiana

I was born in Avon, Indiana.

33
New cards

Mo sì dàgbà ni_______.

I grew up in ______.

34
New cards

Mo sì dàgbà si Avon ni Indiana

I grew up in Avon, Indiana.

35
New cards

Mo wà ní ọdún______.

I am in year ______.

36
New cards

Mo wà ní ọdún keji.

I am in year two.

37
New cards

Mo ní____

I have _____.

38
New cards

Mi ò ní _____

I don’t have ______.

39
New cards

Mo ń kọ́ èdè Yorùbá.

I am learning Yorùbá.

40
New cards

Mo ń ṣiṣẹ́ ní ____.

I work at/in ____.

41
New cards

Èmi náà.

Me too.

42
New cards

Ṣùgbọ́n nísinsìnyí, mo ń gbé ní ____.

But now, I live in ____.

43
New cards

ní

have

44
New cards

Níbo ni ...?

Where ...?

45
New cards

Kí ni ...?

What ...?

46
New cards

Nigba wo ni ______?

When

47
New cards

Ta ni________?

Who

48
New cards

omo odun méloo______?

how old is _______?

49
New cards